Wednesday, September 27, 2017

Ogun Ife kan ni yii odami loju...

Ewe odan 9
Ewe iyeye 9
Ao gun papo Mon ose dudu...
Ofo re ni yii ......
Oju ewure kin si Lara ewe odan , oju aguntan kin si Lara iyeye, Iwo L Omo L ki oju re maa se si Lara emi L Omo L loni .....confirm ni

22 comments:

  1. Baba eseun emi...... Na fe bunyin nikan number mi ni 09071000852

    ReplyDelete
  2. Baba e seen, se obinrin naa le lo mesan mesan

    ReplyDelete
  3. E seun baba ejowo se obirin na le lo mesan

    ReplyDelete
  4. Baba agbayin ma kale,se ekan ni amafi ose na we atipe ago melo,baba ti abamon oruko iya obinrin na unko?toje surname babare lamon?

    ReplyDelete
  5. Baba,Agbaa yin adale o oju yin ko Ni ri ibi o. Ejoo sir mo nfe Ogun itaja aladeun ti a le fi ta properties bi Ile tabi ilee wipe iye ojo bayi Ni afe ki ataa.

    ReplyDelete
  6. Enter your comment...wow modupe oo

    ReplyDelete
  7. Ewe amaje o amin.se dandan ni kamo oruko iya tabi baba eninaa abi ki akan daruko eniyen nikan ni.ejowo baba ebami tan imole si koyemi too

    ReplyDelete
  8. nice baba thank you very much sir

    ReplyDelete
  9. Baba eseun ooo. Ejowo bawo ni lilo ise yi

    ReplyDelete
  10. Baba eseun o agbaayin adale o ejo Sir ti okirin ba felo fun obinrin ti kowa mo oruko iyare Sugbon to o mo ti baba re se ole lo ti Baba re.

    ReplyDelete
  11. E SEUN BABA, EWA A MA JE FUN YIN.

    ReplyDelete
  12. Ejowo mo nilo ose omo Yahoo to daju biku

    ReplyDelete
  13. ESE pupo monilo ise iferan toko taya

    ReplyDelete
  14. Ejo sir, monilo ogun awure obinrin..Iya obinrin nje mi.. 09013689451

    ReplyDelete
  15. Ejo baba,moti gbiyanju oogun orisirisi sugbon oogun okima daun lara mi.

    ReplyDelete
  16. Baba adupe olohun yio bawa dupe fun yin

    ReplyDelete

MOTUN GBE DEOOOO... OSHO OWO TODAJU.

joo nitori OLOHUN ma ko ise sile lai ni seooo.pls do it and confirm.it. EWE BARA OOJO 9,E GUN KUNNA PELU ERU ALAMO IYEKIYE,KIE WA POMO OSE,...