Monday, October 9, 2017

IMULE EBE AWON AGBA (Idarijin Awon Eleye)

Mofe kiaje anfani yi, ni ki Ona letete si funwa nidi Ise ti anse, ati Ninu Irin ajo eda, Ema tele mi............
Ewe Orijin oojo 16, Ewe Ewuro oojo 16, Ewe Lapalapa funfun Oojo 16, Eru alamo 16, Epo obo die, Igi nla die, Ao gun gbogbo repo mo Ose dudu, Ao kosinu fitila Oloju 16, Tia ba kosi fitila na tan, Kogbodo kanle mo, Tiao filo Ose yitan, Ao mafiwe ni Araro ati alale, Odaju ganniooo ,Ebe ati Imule Idarijin awon Eleye to Confirm niooo,
IKILO: Tia batinwe Ose yi kanhinkanhin re ko gbodo jabo, Bi abatin lo Ose yi, Akogbodo je Eran Abiye kankan mo, bi Pepeye, Eyele, Adiye, Turkey, Adan, Eye etu, Tiaofilo tan, Nitori Imule OSA-MEJI Nla tolagbara ni, Ako gbodo tunje Eran kankan namo,
besini, ti abalotan ni ao ma je eran,Leyin ni ti aba gbagbe lati je Eran.Ao da Ose na duro na,Agbudo se Etutu si Nitori,Ki ama bari Ija Eleye

34 comments:

  1. Adupe fun imule ebe awon agba yi. Edakun, ki ni etutu? ki ama bari ija eleye? Ese

    ReplyDelete
    Replies
    1. ese sir ise ti eledua gbeleyin lowo KO nI baje ejo sir kini nkan etutu ti a ba gbagbe latije eran

      Delete
  2. Ese pupo olorun a gbo adura yin.. Ki ni nkan etutu ti eniyan ba gbagbe je eran

    ReplyDelete
  3. Adupe gidigidi lowo eledua to yin she okan lara a won asiwaju rere fun Omo odua patapata, olodumore oni kanju muyin kuro lorile bayi ke gbo ke too ki agba yin odale ase edumare. I jowo kini inkan etutu fun naa, atipe ejowo bawoni asele bayin soro sir

    ReplyDelete
  4. Ese gan inkan yin koni baje ooo Adupe fun imule ebe awon agba yi. Edakun, ki ni etutu? ki ama bari ija eleye?

    ReplyDelete
    Replies
    1. ESE SIR kINI NKAN ETUTU TI ABAGBAGBE LATIJE ERAN

      Delete
  5. Please I need harb for penis to n sunki to Si tunkere

    ReplyDelete
  6. Ejo baba ebawa so nkan etutu funwa tabu kie funwa ni number yin fun ibere sir

    ReplyDelete
  7. Ejo ti o ba ni ki eyun fowo. Ati ki ni elo re

    ReplyDelete
  8. Ejoo nje ti koinkoin ti afi nwe ose na ba jabo se ale paro e?

    ReplyDelete
  9. pls how do i get your contact. plsssssssssss

    ReplyDelete
  10. Edakun, ki ni etutu? ki ama bari ija eleye? Ese

    ReplyDelete
  11. Edakun kinni nkaann etutu naa sir ki a ma ba ri ijaa eleyee?

    ReplyDelete
  12. E dakun kini nkan etutu re sir..

    ReplyDelete
  13. Ese pupo sir olorun a gbo adura yin.. Ki ni nkan etutu ti eniyan ba gbagbe je eran

    ReplyDelete
  14. Enter your comment...ESE sir, ejo sir number yin ni mofe

    ReplyDelete
  15. Ejo kini nkab etutu .atipe to kanhinkanhin ba jabo kini amase

    ReplyDelete
  16. Edakun mini nkan etutu atiwipe ti kainkain ba bosile se ale paro re.

    ReplyDelete
  17. Ewe amaje oooooo, Ase. Mofe di omo egbe yin WhatsApp number re 08093379191.

    ReplyDelete
    Replies
    1. Ewe amaje oooooo, Ase. Mofe di omo egbe yin WhatsApp number re 08091536177..ama ju wa se ase eledua

      Reply

      Delete
  18. Ewe amaje oooooo, Ase. Mofe di omo egbe yin WhatsApp number re 08098408656..ama ju wa se ase eledua

    ReplyDelete
  19. Ejowo kinie inkan etutu atipe bawo ni shishere

    ReplyDelete
  20. E seun sir ejowo kini nkan etutu ati wipe ti kankan naa ba ja bo kini sise Mo dupe sir

    ReplyDelete
  21. Ese gan baba olodu yo wa peluying oo ejowo kin ni inkan atutu baba wa

    ReplyDelete
  22. Thank you sir Ejo sir kini nkan etutu

    ReplyDelete

MOTUN GBE DEOOOO... OSHO OWO TODAJU.

joo nitori OLOHUN ma ko ise sile lai ni seooo.pls do it and confirm.it. EWE BARA OOJO 9,E GUN KUNNA PELU ERU ALAMO IYEKIYE,KIE WA POMO OSE,...