ELO WA EFUN,OSUN,EDU,KIE LO METEETA PAPO MO OSE DUDU,KI E WA FI OSE DUDU YI TEFA EJI OGBE SI OJU OLO,KIE WA PE OHUN RE SI BAYI::EFUN LERIPE OHUNYIO BATI OSUN JE,OSUN LERIPE OHUN YIO BATI EFUN JE,ATI EFUN,ATI OSUN,EDU NIO BATI GBOGBO WON JE,GBOGBO ENITOBARO IBI RO EMI L OMO L,KIBI WON PADA SODO WON.AO KO OSE YI SINU IKE KAN,AO MAA WE LALELALE TI A BA TI FE SUN....HMMMM AROBI TOGBONA NI ATI ASINA...EJO E TETE DAN WOO.KONAWA LOWO PUPO RARA.MON RETI ESIII
Sunday, October 8, 2017
Asina
ewe taba 7 atare eyo 7 a o mu ewe 1 atare1 a o Lo ni enu ona so fi ose ti a le Lo lekan soso ko,ao se be titi ti yio fi pe meje ao MA we ni ojo kankan Tio fi pe ojo meje,ojo meje lowa ninu ose kan eni to ba le gbiyanju e Loni a dupe fun Olohun ni ose ti a ba Lo ise Yi
ARANSE ATI ASINA
ARANSE KIAKIA:
Ori pepeye ako kan, odidi atare kan, ewe sawerepepe, oka burumo pelu haha re ao jopo ao ma fi oti laro
ASINA:
Koro ishin kopo die, ao Jo ao ma fi fo eko mu laaro. Odaju
ASINA
Ao wa owo eyo eyiti ko luju rara ,ao fi ko jankariwo to akoni ri sowo eyo yi Nita rara ao wa gun mo ose ise ekan soso ao jilo we fiwe ni odo to nsan ni arokukutu ni oooo
Sunday, October 1, 2017
AWURE ITAJA
Ako alangba ESO werenjeje aorosi lenu aofi lagba tele ape aoko ewe werejeje lelori pelu odidi atare kan aojopo aomafi eko lolaro epo pupa lale
AJEGUN
Ase oga Ewe alupaida mesan eyo atare mesan ao lo po aofi Singbere yipo orun owo wa
Eyan kan lolelo odaju
Obinrin tobimo tan ti ejekoda
Eko elewe ao bo ewe arare ao bu okele Kan nibe ao fi kan die lara eje yen ao so si enu obinrin naa Walahi eje naa yoo da ni kiakia
MOTUN GBE DEOOOO... OSHO OWO TODAJU.
joo nitori OLOHUN ma ko ise sile lai ni seooo.pls do it and confirm.it. EWE BARA OOJO 9,E GUN KUNNA PELU ERU ALAMO IYEKIYE,KIE WA POMO OSE,...
-
Bi o ba se igba eniyan won yio dari jin e lagbara olorun: ewe aanu, ewe orijin, ewe ooyo, ewe ajeofole, ao toju epo pupa die, ori die, adi ...
-
Ewe odan 9 Ewe iyeye 9 Ao gun papo Mon ose dudu... Ofo re ni yii ...... Oju ewure kin si Lara ewe odan , oju aguntan kin si Lara iyeye,...
-
Mofe kiaje anfani yi, ni ki Ona letete si funwa nidi Ise ti anse, ati Ninu Irin ajo eda, Ema tele mi............ Ewe Orijin oojo 16, Ewe E...