Sunday, October 8, 2017

ASINA

Ao wa owo eyo eyiti ko luju rara  ,ao fi ko jankariwo to akoni ri sowo eyo yi Nita rara ao wa gun mo ose ise ekan soso ao jilo  we fiwe ni odo to nsan ni arokukutu ni oooo

Sunday, October 1, 2017

AWURE ITAJA

Ako alangba ESO werenjeje aorosi lenu aofi lagba tele ape aoko ewe werejeje lelori pelu odidi atare kan aojopo aomafi eko lolaro epo pupa lale

AJEGUN

Ase oga Ewe alupaida mesan eyo atare mesan ao lo po aofi  Singbere yipo orun owo wa
Eyan kan lolelo  odaju

Obinrin tobimo tan ti ejekoda

Eko elewe ao bo ewe arare ao bu okele Kan nibe ao fi kan die lara eje yen ao so si enu obinrin naa Walahi eje naa yoo da ni kiakia

Saturday, September 30, 2017

OGUN GBETUGBETU


*Ao toju owo èyo mèwa ti ko luju, ewe daiko, ewe alupaida èyo meje, ewe orira, odidi atare kan, ao lo awon ewe yèn papo pèlu odidi atare yè, ao toju omo diè to ba sonu lèyin iya rè kan, ao wa la adiè na ni aya, ao bu ogun ti alo yè si ni isalè, ao ko owo èyo le lori, ao wa da ogun yoku le owo èyo lori. Awa de pa mo ara won, awa di papo, ao fi ora yi , ao di ni okun dada ti yio fi jè wipe omi ko le wo inu rè ti aba bo mo inu odo. Odo ti nba nsan dada ni abo mo fun ojo meje. Awa toju aso ipa odè, ao ran ni apo kekere, ti obadi ojo keje, ti aba wu ogun yen ni inu odo, ao ko owo èyo yèn sinu apo ti aran yèn. Lilo rè: ao mun èyo owo èyo kan lowo, ti aba ri awon ole tabi dana-dana, ao ma wa pe ofo rè bayi pe: daiko ki odari won lugbo, orira ki ora won niye, alupaida loni ki won o ma pa oro mi da, èri ki san ko boju wo èyin. Awa na owo wa sinu igbo pe ki won olo ba owa kinni ti oju nu. Awa so owo èyo yè si apo pada. Ako ni ju owo èyo yè si inu igbo, ao kan na owo wa si igbo lasan ni o. Opari!*

OSOLE ATUDE

ako alangba mesan ao to sinu ape ao to atare Medan yipo ao ko idi egbo tude mesan le lori ao Jo ao mafi oti lo o daju gan

OSE BASIRI

Ewe ewuro oojọ , aolọpọ aofi kafura pẹlẹbẹ odindin kan si aofi ọṣẹ ko lori ọlọ
Aoko sinu ike funfun kan
Aomafiwẹ

Okere loju...����

MOTUN GBE DEOOOO... OSHO OWO TODAJU.

joo nitori OLOHUN ma ko ise sile lai ni seooo.pls do it and confirm.it. EWE BARA OOJO 9,E GUN KUNNA PELU ERU ALAMO IYEKIYE,KIE WA POMO OSE,...