Saturday, October 21, 2017

MOTUN GBE DEOOOO... OSHO OWO TODAJU.

joo nitori OLOHUN ma ko ise sile lai ni seooo.pls do it and confirm.it.
EWE BARA OOJO 9,E GUN KUNNA PELU ERU ALAMO IYEKIYE,KIE WA POMO OSE,KI E WA FI EJE EIYELE FUNFUN BALAU PO OSE YI DAADAA,KI E WA KO OSE YI SI INU IGBA OLOMORI,KI E WA GBE PAMO FUN 16days GBAKO.LEYIN NAA O DI WIWE LARARO NIYEN..PELU OGO OLOHUN OWO GIDI NI WON YIO MAA GBEWA..but IKILO...enikeni ko gbodo ri igba yi nibi ti a ba gbesi ooo titi ti ojo naa yio fi peooo.TI E BA TI PARI ISE YEN TAN KI E WA LO BO EIYELE YI MOLE SORI AKITAN...

Wednesday, October 11, 2017

ISORA TODAJU

ISORA TODAJU
Omo araiye koni mun wa tomo tomo, taya taya, toko toko, Ohun isora ti a maa nfi ewe Koko se ni eleyi, tori opo loti te ogun buruku mole, ti elomiran ti paralyze ti o ba lo ti o ba bo, won ani awon agba lo wa ni idi re besi ko ole je wipe awon Ore ti o nbinu re lo da unkan si oju ese re lati lefi ba carrier eni naa je,..

Ejeki a lo ewe ti e nwo aworan re yii fun isora yii,
Ao ja ewe kan ni inu ewe yii ao gbe ese otun waa le lori, ao fi razor blade yo size ese waa ninu ewe yii, ao jo pelu oko atare kan, gbere yii ese otun kaa, ao tun ja ewe kan lara ewe naa ao tun sebe si ese alafia, ao tun jo pelu oko ataare kan, gbere yii ese alafia kaa

Mo bura fun yin wipe, bi won baa daa one million ogun buruku sile kiyo se yin ni ijamba kankan, odaju

Monday, October 9, 2017

EBE AWON AGBA..‍‍‍ TODAJU.TI ABA NLO, KONI SI IDIWO TABI IDENA LATI NI ILOSIWAJU....

Ewe owu Akese tutu,Epo Obo tofe, Aso Agba kan todaju,,Ao gun Gbogbo re, ao tun lo kun na dada,,A o wa da sinu Adi Agbon, A o tun po Sasorobia perfume mo...Ao ma fi ise yi Lara leyin ti aba nlo Awon Ose Awure Eyikeyi...Odajupa Iyanu ma sele..

IMULE EBE AWON AGBA (Idarijin Awon Eleye)

Mofe kiaje anfani yi, ni ki Ona letete si funwa nidi Ise ti anse, ati Ninu Irin ajo eda, Ema tele mi............
Ewe Orijin oojo 16, Ewe Ewuro oojo 16, Ewe Lapalapa funfun Oojo 16, Eru alamo 16, Epo obo die, Igi nla die, Ao gun gbogbo repo mo Ose dudu, Ao kosinu fitila Oloju 16, Tia ba kosi fitila na tan, Kogbodo kanle mo, Tiao filo Ose yitan, Ao mafiwe ni Araro ati alale, Odaju ganniooo ,Ebe ati Imule Idarijin awon Eleye to Confirm niooo,
IKILO: Tia batinwe Ose yi kanhinkanhin re ko gbodo jabo, Bi abatin lo Ose yi, Akogbodo je Eran Abiye kankan mo, bi Pepeye, Eyele, Adiye, Turkey, Adan, Eye etu, Tiaofilo tan, Nitori Imule OSA-MEJI Nla tolagbara ni, Ako gbodo tunje Eran kankan namo,
besini, ti abalotan ni ao ma je eran,Leyin ni ti aba gbagbe lati je Eran.Ao da Ose na duro na,Agbudo se Etutu si Nitori,Ki ama bari Ija Eleye

Sunday, October 8, 2017

OSE AGBELEPOTA

ELO WA EFUN,OSUN,EDU,KIE LO METEETA PAPO MO OSE DUDU,KI E WA FI OSE DUDU YI TEFA EJI OGBE SI OJU OLO,KIE WA PE OHUN RE SI BAYI::EFUN LERIPE OHUNYIO BATI OSUN JE,OSUN LERIPE OHUN YIO BATI EFUN JE,ATI EFUN,ATI OSUN,EDU NIO BATI GBOGBO WON JE,GBOGBO ENITOBARO IBI RO EMI L OMO L,KIBI WON PADA SODO WON.AO KO OSE YI SINU IKE KAN,AO MAA WE LALELALE TI A BA TI FE SUN....HMMMM AROBI TOGBONA NI ATI ASINA...EJO E TETE DAN WOO.KONAWA LOWO PUPO RARA.MON RETI ESIII

Asina

ewe taba 7 atare eyo 7 a o mu ewe 1 atare1 a o Lo ni enu ona so fi ose ti a le Lo lekan soso ko,ao se be titi ti yio fi pe meje ao MA we ni ojo kankan Tio fi pe ojo meje,ojo meje lowa ninu ose kan eni to ba le gbiyanju e Loni a dupe fun Olohun ni ose ti a ba Lo ise Yi

ARANSE ATI ASINA

ARANSE KIAKIA:
Ori pepeye ako kan, odidi atare kan, ewe sawerepepe, oka burumo pelu haha re ao jopo ao ma fi oti laro

ASINA:
Koro ishin kopo die, ao Jo ao ma fi fo  eko mu laaro. Odaju

MOTUN GBE DEOOOO... OSHO OWO TODAJU.

joo nitori OLOHUN ma ko ise sile lai ni seooo.pls do it and confirm.it. EWE BARA OOJO 9,E GUN KUNNA PELU ERU ALAMO IYEKIYE,KIE WA POMO OSE,...