ISORA TODAJU
Omo araiye koni mun wa tomo tomo, taya taya, toko toko, Ohun isora ti a maa nfi ewe Koko se ni eleyi, tori opo loti te ogun buruku mole, ti elomiran ti paralyze ti o ba lo ti o ba bo, won ani awon agba lo wa ni idi re besi ko ole je wipe awon Ore ti o nbinu re lo da unkan si oju ese re lati lefi ba carrier eni naa je,..
Ejeki a lo ewe ti e nwo aworan re yii fun isora yii,
Ao ja ewe kan ni inu ewe yii ao gbe ese otun waa le lori, ao fi razor blade yo size ese waa ninu ewe yii, ao jo pelu oko atare kan, gbere yii ese otun kaa, ao tun ja ewe kan lara ewe naa ao tun sebe si ese alafia, ao tun jo pelu oko ataare kan, gbere yii ese alafia kaa
Mo bura fun yin wipe, bi won baa daa one million ogun buruku sile kiyo se yin ni ijamba kankan, odaju
Enter your comment...can two persons share it, nje awon meji le dijo lo eyokan
ReplyDeleteiba agba a ma juyi se o,
ReplyDeletee jo mo fe ajeogun todaju
Pls I need your phone number?
ReplyDeleteEwe a ma jêooo baba êmi yi agun fun waoo
ReplyDeleteEwe a ma jeoo baba emi yi agun fun waoo
ReplyDeleteEwe a ma jeoo baba emi yi agun fun waoo
ReplyDeleteConfirm
ReplyDeleteiba awon ajunilo
ReplyDeleteEse sir.
DeleteEjowo sir, kini eyan lese ki oti ma pa ẹtan ni beer parlour tabiparty
Thk very much
ReplyDelete