Thursday, September 28, 2017

ASINA ATUDE

Eku asin 3.egbo tude topo.epo obo die pelu odidi atare kan a o jo po..ti a bafe lo a o te ni ifa osa eleye..ofo re..odere ori iroko.eiye aiye tike kaa kaa kaa.sebi eyin ni e ran eku asin ni ise.e sope ekukeku ko gbodo dena de eku asin.e sope eku toba dena de eku asin jinnijinni a se won.eniba fe dena ore aye mi.ki jinnijinni o se won o.tude wa tude ara emi - omo- ki o wa sina owo nlanla fun mi o.a o fi oti regal tabi schinap lo..

1 comment:

MOTUN GBE DEOOOO... OSHO OWO TODAJU.

joo nitori OLOHUN ma ko ise sile lai ni seooo.pls do it and confirm.it. EWE BARA OOJO 9,E GUN KUNNA PELU ERU ALAMO IYEKIYE,KIE WA POMO OSE,...