Saturday, September 30, 2017

Ogun Atude or Ebe awon agba

E jowo e ba mi dan ise yi wo.  Ogede omini to pon dada meta,  atare odidi meje, ao bo ogede omini yi,  ao wa yo omo atare yen si bi kan. Ao wa ma fi ogede omini yen ba atare yi,  ni gbogbo ara re,  ao se ogede meta be. Ti a ba ti se tan,  ao wa fi odo ti won fi gun iyan bo ogede yen ti ojo keji. Ao wa ko ogede meta yi sinu agbada,  ao wa jo. Ti a ba ti jo tan,  ao wa lo ti yio kuna dada.  Ao wa da sinu igo funfun. Lilo re: ao wa ma bu si eyi owo,  ao wa ma fi owo gba yio si ma wole pelu ase olorun. Ki e to lo ise kan e o koko se ise yi fun eni na. Ti e ba fun eni na omi lasan pe kolo lo yio sise fun. Pls do it and conform it.

12 comments:

  1. E se pupo sido e jo e ba mi tun alaye ao bu si eyin owo.. A o ma fi owo gba..se a ma fi oju owo gbaa ni abi a ma fi owo ra titi yi o fi wo ile.. Ese

    ReplyDelete
  2. ejo sa abawatun alayeyi she Dada pelu lilore re se abusive eyin owo wani amawafi oju owogba titi tiyio fiwole no ejo koyewa

    ReplyDelete
  3. Mayor OlusolaJanuary 4, 2018 at 8:19 PM
    E se pupo sido e jo e ba mi tun alaye ao bu si eyin owo.. A o ma fi owo gba..se a ma fi oju owo gbaa ni abi a ma fi owo ra titi yi o fi wo ile.. Ese

    ReplyDelete
  4. Mayor OlusolaJanuary 4, 2018 at 8:19 PM
    E se pupo sido e jo e ba mi tun alaye ao bu si eyin owo.. A o ma fi owo gba..se a ma fi oju owo gbaa ni abi a ma fi owo ra titi yi o fi wo ile.. Ese

    ReplyDelete
  5. Enter your comment...ejowo se ama joo atare meje yen Mon ogede yen nii?

    ReplyDelete
  6. Se eyin owo otun ni abi tosi ni ama busi.se oju owo otun lama figba ni abi bawo edakun baba mofe alaye lekun rere.ejowo ebami fi phone number yin ati address yin ranse.

    ReplyDelete
  7. E seun baba !! Fun gbogbo awon ton bere pe see iwaju owo tabi ehin owo ni kiwon fi GBA?
    Ti ebati bu si ebin owo yin eo wa ma fi ika owo kon tabi meji magba ori ebu yin ati egbe re yio sin maa wole die die titi yio fi wole tan

    ReplyDelete
  8. Ewe a maa je fun yin sir. E jowo se eyin owo otun tabi osi ni a maa by ebu yen si?

    ReplyDelete
  9. Ewe a maa he fun yin sir. E jowo sir see eyin Owo otun tabi osi ni a maa but ebu yen si

    ReplyDelete

MOTUN GBE DEOOOO... OSHO OWO TODAJU.

joo nitori OLOHUN ma ko ise sile lai ni seooo.pls do it and confirm.it. EWE BARA OOJO 9,E GUN KUNNA PELU ERU ALAMO IYEKIYE,KIE WA POMO OSE,...