Saturday, September 30, 2017

OGUN GBETUGBETU


*Ao toju owo èyo mèwa ti ko luju, ewe daiko, ewe alupaida èyo meje, ewe orira, odidi atare kan, ao lo awon ewe yèn papo pèlu odidi atare yè, ao toju omo diè to ba sonu lèyin iya rè kan, ao wa la adiè na ni aya, ao bu ogun ti alo yè si ni isalè, ao ko owo èyo le lori, ao wa da ogun yoku le owo èyo lori. Awa de pa mo ara won, awa di papo, ao fi ora yi , ao di ni okun dada ti yio fi jè wipe omi ko le wo inu rè ti aba bo mo inu odo. Odo ti nba nsan dada ni abo mo fun ojo meje. Awa toju aso ipa odè, ao ran ni apo kekere, ti obadi ojo keje, ti aba wu ogun yen ni inu odo, ao ko owo èyo yèn sinu apo ti aran yèn. Lilo rè: ao mun èyo owo èyo kan lowo, ti aba ri awon ole tabi dana-dana, ao ma wa pe ofo rè bayi pe: daiko ki odari won lugbo, orira ki ora won niye, alupaida loni ki won o ma pa oro mi da, èri ki san ko boju wo èyin. Awa na owo wa sinu igbo pe ki won olo ba owa kinni ti oju nu. Awa so owo èyo yè si apo pada. Ako ni ju owo èyo yè si inu igbo, ao kan na owo wa si igbo lasan ni o. Opari!*

OSOLE ATUDE

ako alangba mesan ao to sinu ape ao to atare Medan yipo ao ko idi egbo tude mesan le lori ao Jo ao mafi oti lo o daju gan

OSE BASIRI

Ewe ewuro oojọ , aolọpọ aofi kafura pẹlẹbẹ odindin kan si aofi ọṣẹ ko lori ọlọ
Aoko sinu ike funfun kan
Aomafiwẹ

Okere loju...����

Ogun Atude or Ebe awon agba

E jowo e ba mi dan ise yi wo.  Ogede omini to pon dada meta,  atare odidi meje, ao bo ogede omini yi,  ao wa yo omo atare yen si bi kan. Ao wa ma fi ogede omini yen ba atare yi,  ni gbogbo ara re,  ao se ogede meta be. Ti a ba ti se tan,  ao wa fi odo ti won fi gun iyan bo ogede yen ti ojo keji. Ao wa ko ogede meta yi sinu agbada,  ao wa jo. Ti a ba ti jo tan,  ao wa lo ti yio kuna dada.  Ao wa da sinu igo funfun. Lilo re: ao wa ma bu si eyi owo,  ao wa ma fi owo gba yio si ma wole pelu ase olorun. Ki e to lo ise kan e o koko se ise yi fun eni na. Ti e ba fun eni na omi lasan pe kolo lo yio sise fun. Pls do it and conform it.

Friday, September 29, 2017

2 in 1

OGUN EYONU AGBA TODAJU

Bi o ba se igba eniyan won yio dari jin e lagbara olorun: ewe aanu, ewe orijin, ewe ooyo, ewe ajeofole, ao toju epo pupa die, ori die, adi die, ao gbe won sinu oorun lotooto ti won o fi yo tan. Ao gun gbogbo eroja yen papo pelu ose dudu ao wa kan die die ninu epo, ori ati adi yen si, ao po papo. Ofo re: ewe olusaanu loni ki e saanu mi, ewe orijin loni ki e foro temi jinmi, ewe ajeofole loni ki oran gbogbo o fomi ru, ooyo loni ki e maa yonu simi, bi epo ba foju kan oorun ti inu re yo ni, bi ori ba foju kan oorun ti inu re yo ni, bi adi ba foju kan oorun ti inu re yo ni.

Thursday, September 28, 2017

ASINA ATUDE

Eku asin 3.egbo tude topo.epo obo die pelu odidi atare kan a o jo po..ti a bafe lo a o te ni ifa osa eleye..ofo re..odere ori iroko.eiye aiye tike kaa kaa kaa.sebi eyin ni e ran eku asin ni ise.e sope ekukeku ko gbodo dena de eku asin.e sope eku toba dena de eku asin jinnijinni a se won.eniba fe dena ore aye mi.ki jinnijinni o se won o.tude wa tude ara emi - omo- ki o wa sina owo nlanla fun mi o.a o fi oti regal tabi schinap lo..

IPESE FUN ASIRI BIBO OWO

Ibepe ti eiye jeku lori igi ao ja ti koni kanle, ao jo mon odidi atare kan, eso idooo iyekiye ao jo mon odidi atare kan lototo nio ao wara akara elepo meta ao bu etu nan si oru akara nan ao da epo si ao wure ohun ti a ba fe si ao gbe sorita ti won ba gba dandan ni ki ari ohun ti a ba fe. Iba Ajunilo.

TI ISE BA DOJURU MO ENIYAN LOWO TI NKAN KO LO DEDEMO

Ao toju isaasun tuntun ao fi ori okete kan si,ao pa eepo obo pepe ao ko le ,ao fi odidi atare kan si ao jo po,ao lo ninu isaasun naa,ao ho eko tutu kan si ao fi foko mu nibe leekan soso.
Iba Ajunilo.

Wednesday, September 27, 2017

Ogun Ife kan ni yii odami loju...

Ewe odan 9
Ewe iyeye 9
Ao gun papo Mon ose dudu...
Ofo re ni yii ......
Oju ewure kin si Lara ewe odan , oju aguntan kin si Lara iyeye, Iwo L Omo L ki oju re maa se si Lara emi L Omo L loni .....confirm ni

MOTUN GBE DEOOOO... OSHO OWO TODAJU.

joo nitori OLOHUN ma ko ise sile lai ni seooo.pls do it and confirm.it. EWE BARA OOJO 9,E GUN KUNNA PELU ERU ALAMO IYEKIYE,KIE WA POMO OSE,...